From 26adfea0128e349c1181d8e71f5f2c27b550d8cb Mon Sep 17 00:00:00 2001
From: Mozilla L10n Automation Bot
Date: Mon, 23 May 2022 00:04:34 +0000
Subject: [PATCH] Import l10n.
---
.../src/main/res/values-eo/strings.xml | 12 +-
.../src/main/res/values-yo/strings.xml | 228 ++++++++++++++++++
.../addons/src/main/res/values-ur/strings.xml | 2 +-
.../src/main/res/values-eo/strings.xml | 8 +-
.../src/main/res/values-eo/strings.xml | 10 +-
.../src/main/res/values-eo/strings.xml | 6 +
.../crash/src/main/res/values-eo/strings.xml | 3 +
7 files changed, 261 insertions(+), 8 deletions(-)
diff --git a/components/browser/errorpages/src/main/res/values-eo/strings.xml b/components/browser/errorpages/src/main/res/values-eo/strings.xml
index 8a55f6aa314..a34416bc5f1 100644
--- a/components/browser/errorpages/src/main/res/values-eo/strings.xml
+++ b/components/browser/errorpages/src/main/res/values-eo/strings.xml
@@ -1,14 +1,9 @@
-
- Problemo dum ŝargado de paĝoKlopodi denove
-
- Reen
-
Ne eblas kompletigi la peton
@@ -234,4 +229,11 @@ la eraro povas esti tempa kaj vi povos klopodi denove poste.
Problemo kun trompa retejoTiu ĉi paĝo ĉe %1$s estis denuncita kiel trompa retejo, kaj ĝi estis blokita surbaze de viaj sekurecaj preferoj.
]]>
+
+
+ Sekura retejo ne disponebla
+
+ %1$s ne estas disponebla.]]>
+
+ Daŭrigi al retejo HTTP
diff --git a/components/browser/errorpages/src/main/res/values-yo/strings.xml b/components/browser/errorpages/src/main/res/values-yo/strings.xml
index 578ec13d98d..7f009ddb9fd 100644
--- a/components/browser/errorpages/src/main/res/values-yo/strings.xml
+++ b/components/browser/errorpages/src/main/res/values-yo/strings.xml
@@ -14,4 +14,232 @@
Ìsomọ́ra Onífọ̀kànbalẹ̀ Kùnà
+
+
+
ojú-ìwé tí ò ń gbìyànjú àti wò, kò ṣe é fi hàn báyìí nítorí pé ìjẹ́-òtítọ́ data tí a gbà ni a kò lè fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀.
+
Jọ̀wọ́ kàn sí ẹni tí ó ni ìkànnì náà láti fi ìsòro yìí tó wọn létí.
+
+ ]]>
+
+
+ Ìsomọ́ra onífọkànbalẹ̀ kùnà
+
+
+
+
Ìsòro yìí lè jẹ́ ìfisáfà ṣiṣẹ́ tàbí kí ẹlòmíràn fẹ́ gbáwọ̀ sáfà wọ̀.
+
Bí o bá ti ṣe àṣeyege àti wọlé sórí sáfà yìí tẹ́lẹ̀ rí, àsìṣe náà lè jẹ́ èyí tí kò ní pẹ́, ó sì le gbìyànjú sí i bó bá yá .
+
+ ]]>
+
+
+ Ìjìnlẹ̀…
+
+ Ẹnìkan le máa gbìyànjú àti gbáwọ̀ ìkànnì náà wọ̀, má tẹ̀síwájú.
+
+
+ ]]>
+
+
+ Padà Sẹ́yìn (Ìmọ̀ràn tó dára)
+
+ Gba Ewu náà kí o sì tẹ̀síwájú
+
+
+ Akùdé bá ìsomọ́ra náà
+
+
+ ìtàkùn ìgbáyé so mọ́ra dáadáa, ṣùgbọ́n àkùdé bá ìsomọ́ra náà nígbà tí à ń fi ìfitónilétí ránṣẹ́. Jọ̀wọ́ gbìyànjú sí i.
+
+
Ìkànnì náà lè má siṣẹ́ fún ìgbà díẹ̀ tàbí kí ọwọ́ kún un. Gbìyànjú rẹ̀ sí i ní àìpẹ́.
+
Bí o kò bá lè jẹ́ kí ojú-ìwé rẹ siṣẹ́, yẹ ohun tí data rẹ fi ń siṣẹ́ wò tàbí ìsomọ́ Wi-Fi rẹ.
+
+ ]]>
+
+
+ Àkókò ìsomọ́ ti kọjá
+
+
+ Ìkànnì tí ó bèèrè kò dáhùn sí ìsomọ́ ti o béèrè àti pé ìtàkùn àgbáyé ti dúró iṣẹ́, ó ń dúró fún èsì.
+
+
Ǹjẹ́ ó ṣe é ṣe kí sáfà máa dojúkọ ìpè púpọ̀ tàbí kí ó má ṣiṣẹ́ fún ìgbà díẹ̀? Gbìyànjú bí ó bá yá.
+
Ǹjẹ́ o ní ìṣòro àti sàwárí àwọn ìkànnì mìíràn? Yẹ ohun tí o fi ṣe àsomọ́ wò.
+
Ǹjẹ́ ìdáabòbò ohun èlò rẹ tàbí nẹ́tíwòkì jẹ́ láti ọwọ́ ojúlówó tàbí asojú? àsìsẹ ààtò lè nípa lórí wíwá nǹkna lórí ìkànnì.
+
O sì ní ìsòro síbẹ̀? Kàn sí alákòóso nẹ́tiwọkì rẹ tàbí àpèse íntánẹ́ẹ̀tì rẹ fún ìrànlọ́wọ́.
+
+ ]]>
+
+
+ Kùnà láti somọ́ra
+
+
+
Ìkànnì náà lè má sí ní àrọ́wọ́tó fún ìgbà díẹ̀ tàbí kí ọwọ́ kún un. Gbìyànjú sí i láìpẹ́.
+
Bí o kò bá lè jẹ́ kí ojú-ìwé siṣẹ́, yẹ ohun èlò data rẹ wò tàbí àsomọ́ Wi-Fi.
+
+ ]]>
+
+
+ Èsì tí a kò retí láti ọ̀dọ̀ sáfà
+
+
+ Ìkànnì ń fèsì sí nẹ́tíwọ̀kì lọ́nà ti a kò retí àti pé ìtàkùn àgbáyé kò le tẹ̀síwájú.
+ ]]>
+
+
+ Ojú-ìwé náà kò ṣe atọ̀nà dáadáa
+
+ ìtàkùn àgbáyé dáwọ́ àtimú àwọn ohun tí a bèèrè dúró. Ìkànnì náà ń ṣe àtúntọ́sọ́nà lọ́nà tí kò lè parí láéláé.
+
+
Ǹjẹ́ o ti ṣo ọ́ di aláìlágbára tàbí dínà àwọn adásiṣẹ́ tí ìkànnì yìí nílò?
+
Bí gbígba àwọn adásiṣẹ́ ìkànnì yìí kò bá yanjú ìsòro yìí, a jẹ́ pé ó ṣe é ṣe kí ó jẹ́ ìsòro ìfisáfàṣiṣẹ́ ni, kìí sì ṣe ohun èlò rẹ.
+
+ ]]>
+
+
+ Ipò àìsí lórí íntánẹ́ẹ̀tì
+
+
+ Ìtàkùn-àgbáyé ń ṣiṣẹ́ lóríipò àìsí lórí íntánẹ́ẹ̀tì, nítorí náà, kò lè so mọ́ ohun tí a bèèrè fún.
+
+
Ǹjẹ́ ohun èlò náà wà ní sísomọ́ nẹ́tíwọ̀kì tó ń ṣiṣẹ́?
+
Tẹ “Gbìyànjú sí i” láti bọ́ sí ipo íntánẹ́ẹ̀tì, kí o si ojú-ìwé náà siṣẹ́ lẹ́ẹ̀kan sí.
+
+ ]]>
+
+
+ Ojú yìí kò ṣiṣẹ́ nítorí ààbò
+
+ Àdírẹ́sì tí o bèèrè fún nílò ojú kan pàtó (e.g., mozilla.org:80 fún ojú 80 lórí mozilla.org) ni a máa ń sábà lò fún àwọn ìdí yàtọ̀ sí ìwá nǹkan kíri orí ìkànnì. Ìtàkùn-àgbáyé ti gbégi lé ìbéérè náà fún ààbò rẹ.
+ ]]>
+
+
+ Ìsomọ́ra di àtúntò
+
+
+ Akùdé bá òpónà nẹ́tíwọ̀kì nígbà tí ìdúnàándúrà ìsomọ́ra ń lọ lọ́wọ́. Jọ̀wọ́ gbìyànjú sí i.
+
+
Ìkànnì náà lè má siṣẹ́ fún ìgbà díẹ̀ tàbí kí ọwọ́ kún un. Gbìyànjú lẹ́yìn ìgbà díẹ̀.
+
Bí o kò bá lè jẹ́ kí ojú ìwé kankan siṣẹ́, yẹ ohun èlò data rẹ wò tàbí ìsomọ́ Wi-Fi.
+
+ ]]>
+
+
+ Ẹ̀yà fáìlì tó léwu
+
+
+
Jọ̀wọ́ kàn sí àwọn tí ó ni ìkànnì láti fi ìsòro yìí tó wọn létí.
+
+ ]]>
+
+
+ Àṣìṣe ìbàjẹ́ àkóónú
+
+
+ Ojú-ìwé tí ò ń gbìyànjú àti wò kò ṣe é fihàn nítorí pé a rí àṣìṣe kan nínú data fífiránṣẹ́.
+
+
Jọ̀wọ́ kan sí àwọn tí ó ni ìkànnì láti fi ìsòro yìí tó wọn létí.
+
+ ]]>
+
+
+ Àkóónú ti bàjẹ́
+ Ojú-ìwé tí ò ń gbíyànjú àti wò kò ṣe é fi hàn nítorí pé, a rí àṣìṣe kan nínú ìfidátà ránsẹ́.
+
+
Jọ̀wọ́ kàn sí àwọn tó ni ìkànnì láti fi ìsòro yìí tó wọn létí.
+
+ ]]>
+
+
+ Àṣìṣe ìṣàrokò àkóónú
+
+ Ojú-iwé tí ò ń gbìyànjú àti wò kò ṣe é fi hàn nítorí tí ó le ìsọdikékeré alápiṣeégbà tàbí aláìfọwọ́sí.
+
+
Jọ̀wọ́ kàn sí àwọn tí wọ́n ni ìkànnì láti fi ìsòro yìí tó wọn létí.
+
+ ]]>
+
+
+ A kò rí àdírẹ́sì
+
+ Ìtàkùn-àgbáyé kò rí agbàlejò sáfà fún àdírẹ́sì.
+
+
yẹ àdírẹ́sì náà wò fún àṣìtẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i
+ ww.example.com dípò
+ www.example.com.
+
Bí o kò bá lè mú kí ojú ìwé kankan ṣiṣẹ́, yẹ ohun èlò data rẹ wò tàbí ìsomọ́ Wi-Fi.
+
+ ]]>
+
+
+ Kò sí ìsomọ́ íntánẹ́ẹ̀tì
+
+ Yẹ àsomọ́ nẹ́tiwọ̀kì rẹ wò tàbí gbìyànjú àti mú ojú-ìwé ṣiṣẹ́ lẹ́yìn ìgbà díẹ̀
+
+
+ Tún mú un ṣiṣẹ́
+
+
+ Àdírẹ́sì aláìṣeégbà
+
+ Àdírẹ́sì tí o pèsè kò sí ní ìlànà tí a dámọ̀. Jọ̀wọ́ yẹ àmì ìfi-ọ̀gangan-hàn wò fún àṣìṣe, kì ò sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan sí i.
+ ]]>
+
+ Àdírẹ́sì náà kò ṣe é gbà
+
+
+
Àdírẹ́sì ìkànnì ni a sábà máa ń kọ bí i http://www.example.com/
+
Rí i dájú pé àkámọ́ asùnsọ́wọ́-wájú ni ò ń lò (b.a. /).
+
+ ]]>
+
+
+ Ìlànà tí a kò mọ̀
+
+ Àdírẹ́sì náà sọ ìlànà kan (e.g., wxyz://) ìtàkùn-àgbáyé kò dá a mọ̀, nítorí náà àtàkùn-àgbáyé kò lè so ó mọ́ ìkànnì.
+
+
Ǹjẹ́ ò gbìyànjú àti ní àǹfààní sí ìbánisọ̀rọ̀-alárànbarà tàbí àwọn iṣẹ́ mìíràn tí kìí ṣe alátẹ̀jíṣẹ́? Wo ìkànnì náà fún àwọn ìbéérè tí ó tún kù.
+
Àwọn ìlànà mìíràn a máa alàgàta amẹ́rọṣiṣẹ́ kí ìtàkùn-àgbáyé tó lè dá wọn mọ̀.
+
+ ]]>
+
+
+ A kò rí fáìlì
+
+
+
Ǹjẹ́ a lè ti pa orúkọ nǹkan náà dà, yọ ọ́ kúrò tàbí mú un lọ síbòmíràn?
+
Ǹjẹ́ àṣìṣe wa lè wà níbi sípẹ́lì, ìlo-lẹ́tà-ńlá, tàbí àṣìtẹ̀ níbi àdírẹ́sì bí?
+
Ǹjẹ́ o ní ìyọ́nda tótó fún ohun tí ò ń bèèrè?
+
+ ]]>
+
+
+ Ìdènà wà sí àṣe sí fáìlì náà
+
+
Ó ṣe é ṣe kí wọ́n ti yọ ọ́, gbé e tàbí àṣẹ sí fáìlì lè máa dènà àti wọlé.
+
+ ]]>
+
+
+ Asojú sáfà kọ asomọ́ra
+
diff --git a/components/feature/addons/src/main/res/values-ur/strings.xml b/components/feature/addons/src/main/res/values-ur/strings.xml
index 0e23d1fe77b..714a1cc8d3d 100644
--- a/components/feature/addons/src/main/res/values-ur/strings.xml
+++ b/components/feature/addons/src/main/res/values-ur/strings.xml
@@ -29,7 +29,7 @@
گشت کاری کے دوران برائزر کی سرگرمی کی رسائی
- نشانیاں پڑھیں اور ترمیم کریں
+ بک مارک پڑھیں اور ترمیم کریںرازداری سیٹکگیں پڑھیں اور ترمیم کریں
diff --git a/components/feature/downloads/src/main/res/values-eo/strings.xml b/components/feature/downloads/src/main/res/values-eo/strings.xml
index 29ca049463f..dc042665017 100644
--- a/components/feature/downloads/src/main/res/values-eo/strings.xml
+++ b/components/feature/downloads/src/main/res/values-eo/strings.xml
@@ -47,6 +47,12 @@
La permeso aliri la konservejon de dosieroj kaj aŭdvidaĵojn estas bezonata por elŝuti dosierojn. Iru al la agordoj de Android, tuŝetu Permesoj kaj poste Permesi.
+
+ Ĉu nuligi privatajn elŝutojn?
+
+ Se vi fermas ĉiujn viajn langetojn de privata retumo nun, %1$s elŝutoj estos nuligitaj. Ĉu vi certe volas forlasi la privatan retumon?Nuligi elŝutojn
-
+
+ Resti en privata retumo
+
diff --git a/components/feature/prompts/src/main/res/values-eo/strings.xml b/components/feature/prompts/src/main/res/values-eo/strings.xml
index 6cf7b9e5889..b2ac9708d84 100644
--- a/components/feature/prompts/src/main/res/values-eo/strings.xml
+++ b/components/feature/prompts/src/main/res/values-eo/strings.xml
@@ -20,6 +20,8 @@
Ne konserviNeniam konservi
+
+ Ne nunKonservi
@@ -103,6 +105,12 @@
Malfaldi sugestitajn kreditkartojnFaldi sugestitajn kreditkartojn
-
+
Administri kreditkartojn
+
+ Ĉu sekure konservi tiun ĉi kreditkarton?
+
+ Ĉu ĝisdatigi la daton de senvalidiĝo de kreditkarto?
+
+ La numero de kreditkaro estos ĉifrita. La sekureca kodo ne estos konservita.
diff --git a/components/feature/sitepermissions/src/main/res/values-eo/strings.xml b/components/feature/sitepermissions/src/main/res/values-eo/strings.xml
index 9aad696e6d8..28326bfb5cf 100644
--- a/components/feature/sitepermissions/src/main/res/values-eo/strings.xml
+++ b/components/feature/sitepermissions/src/main/res/values-eo/strings.xml
@@ -35,6 +35,12 @@
Ĉu permesi al %1$s konservi datumojn en konstanta konservejo?Ĉu permesi al %1$s ludi enhavon protektitan de DRM?
+
+ Ĉu permesi al %1$s uzi siajn kuketojn en %2$s?
+
+ Vi povus voli bloki la aliron, se ne estas klare, kial %s bezonas tiujn ĉi datumojn.Pli da informo
diff --git a/components/lib/crash/src/main/res/values-eo/strings.xml b/components/lib/crash/src/main/res/values-eo/strings.xml
index fd914bdd176..068ead76d24 100644
--- a/components/lib/crash/src/main/res/values-eo/strings.xml
+++ b/components/lib/crash/src/main/res/values-eo/strings.xml
@@ -16,6 +16,9 @@
Paneoj
+
+ Bedaŭrinde problemo okazis en %1$s.
+
Raporto